Nọmba 25:8 BM

8 ó tọ ọkunrin náà lọ ninu àgọ́ rẹ̀, ó sì fi ọ̀kọ̀ náà gún òun ati obinrin náà ní àgúnyọ. Àjàkálẹ̀ àrùn sì dúró láàrin àwọn ọmọ Israẹli.

Ka pipe ipin Nọmba 25

Wo Nọmba 25:8 ni o tọ