Nọmba 26:37 BM

37 Gbogbo àwọn tí a kà ninu ẹ̀yà Efuraimu jẹ́ ẹgbaa mẹrindinlogun ó lé ẹẹdẹgbẹta (32,500). Àwọn ni ọmọ Josẹfu ní ìdílé-ìdílé.

Ka pipe ipin Nọmba 26

Wo Nọmba 26:37 ni o tọ