Nọmba 26:65 BM

65 Nítorí pé OLUWA ti sọ pé gbogbo àwọn ti ìgbà náà ni yóo kú ninu aṣálẹ̀. Kalebu ọmọ Jefune ati Joṣua ọmọ Nuni nìkan ni ó kù lára wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 26

Wo Nọmba 26:65 ni o tọ