Nọmba 27:8 BM

8 Sì sọ fún àwọn ọmọ Israẹli pé nígbà tí ẹnìkan bá kú láìní ọmọkunrin, àwọn ọmọbinrin rẹ̀ yóo jogún ilẹ̀ ìní rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 27

Wo Nọmba 27:8 ni o tọ