Nọmba 3:28 BM

28 Gbogbo àwọn ọkunrin tí a kà ninu wọn láti ọmọ oṣù kan sókè jẹ́ ẹgbaarin ó lé ẹgbẹta (8,600). Àwọn ni wọ́n ń ṣe ìtọ́jú ibi mímọ́.

Ka pipe ipin Nọmba 3

Wo Nọmba 3:28 ni o tọ