Nọmba 31:3 BM

3 Mose bá sọ fún àwọn eniyan náà pé, “Ẹ múra ogun kí á lè gbógun ti àwọn ará Midiani, kí á sì fìyà jẹ wọ́n fún ohun tí wọ́n ṣe sí OLUWA.

Ka pipe ipin Nọmba 31

Wo Nọmba 31:3 ni o tọ