Nọmba 31:52 BM

52 Ìwọ̀n gbogbo ọrẹ ẹbọ tí àwọn olórí ogun náà mú wá jẹ́ ẹgbaajọ ó lé ẹẹdẹgbẹrin ó lé aadọta (16,750) ṣekeli.

Ka pipe ipin Nọmba 31

Wo Nọmba 31:52 ni o tọ