Nọmba 31:6 BM

6 Mose sì rán wọn lọ sójú ogun lábẹ́ àṣẹ Finehasi ọmọ Eleasari alufaa, pẹlu àwọn ohun èlò mímọ́ ati fèrè fún ìdágìrì lọ́wọ́ rẹ̀.

Ka pipe ipin Nọmba 31

Wo Nọmba 31:6 ni o tọ