Nọmba 31:9 BM

9 Àwọn ọmọ Israẹli kó àwọn obinrin ati àwọn ọmọ Midiani lẹ́rú. Wọ́n kó gbogbo ẹran ọ̀sìn wọn ati gbogbo agbo ẹran wọn ati gbogbo ohun ìní wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 31

Wo Nọmba 31:9 ni o tọ