Nọmba 32:13 BM

13 Ibinu OLUWA ru sí àwọn ọmọ Israẹli, ó sì mú wọn rìn kiri ninu aṣálẹ̀ fún ogoji ọdún títí gbogbo àwọn tí wọ́n ṣe burúkú níwájú OLUWA fi kú tán.

Ka pipe ipin Nọmba 32

Wo Nọmba 32:13 ni o tọ