Nọmba 32:21 BM

21 tí àwọn ọmọ ogun yín sì ṣetán láti ré odò Jọdani kọjá ní àṣẹ OLUWA láti gbógun ti àwọn ọ̀tá wa títí OLUWA yóo fi pa wọ́n run,

Ka pipe ipin Nọmba 32

Wo Nọmba 32:21 ni o tọ