Nọmba 32:30 BM

30 Ṣugbọn bí wọn kò bá bá yín ré odò Jọdani kọjá, tí wọn kò sì lọ sí ojú ogun pẹlu yín, wọn óo gba ìpín ilẹ̀ ìní tiwọn ní Kenaani bíi àwọn ọmọ Israẹli yòókù.”

Ka pipe ipin Nọmba 32

Wo Nọmba 32:30 ni o tọ