Nọmba 33:1 BM

1 Ibi tí àwọn ọmọ Israẹli pàgọ́ sí ninu ìrìn àjò wọn láti ìgbà tí wọn ti kúrò ní Ijipti lábẹ́ àṣẹ Mose ati Aaroni nìwọ̀nyí:

Ka pipe ipin Nọmba 33

Wo Nọmba 33:1 ni o tọ