Nọmba 36:6 BM

6 nítorí náà OLUWA wí pé àwọn ọmọbinrin Selofehadi ní ẹ̀tọ́ láti fẹ́ ẹnikẹ́ni tí ó wù wọ́n, ṣugbọn ó gbọdọ̀ jẹ́ láti inú ẹ̀yà wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 36

Wo Nọmba 36:6 ni o tọ