Nọmba 5:3 BM

3 Ẹ kó wọn sí ẹ̀yìn odi kí wọn má baà sọ ibùdó yín di aláìmọ́ nítorí pé mò ń gbé inú rẹ̀ pẹlu àwọn eniyan mi.”

Ka pipe ipin Nọmba 5

Wo Nọmba 5:3 ni o tọ