24 ‘Kí OLUWA bukun yín,kí ó sì pa yín mọ́.
25 Kí OLUWA mú kí ojú rẹ̀ mọ́lẹ̀ sí yín lára,kí ó sì ṣàánú fún yín.
26 Kí OLUWA bojúwò yín,kí ó sì fún yín ní alaafia.’
27 “Bẹ́ẹ̀ ni wọn óo fi orúkọ mi súre fún àwọn ọmọ Israẹli, n óo sì bukun wọn.”