Nọmba 7:10 BM

10 Àwọn olórí náà rú ẹbọ fún ìyàsímímọ́ pẹpẹ ní ọjọ́ tí wọ́n ta òróró sí i, láti yà á sí mímọ́. Wọ́n mú ẹbọ wọn wá siwaju pẹpẹ.

Ka pipe ipin Nọmba 7

Wo Nọmba 7:10 ni o tọ