Nọmba 8:11 BM

11 kí Aaroni alufaa wá ya àwọn ọmọ Lefi sọ́tọ̀ bí ọrẹ fífì láti ọ̀dọ̀ àwọn ọmọ Israẹli, kí wọ́n lè máa ṣe iṣẹ́ ìsìn OLÚWA.

Ka pipe ipin Nọmba 8

Wo Nọmba 8:11 ni o tọ