Nọmba 9:3 BM

3 Ní ọjọ́ kẹrinla oṣù yìí, láti àṣáálẹ́ ni àwọn ọmọ Israẹli yóo ti máa ṣe Àjọ̀dún ìrékọjá gẹ́gẹ́ bí òfin ati ìlànà rẹ̀.”

Ka pipe ipin Nọmba 9

Wo Nọmba 9:3 ni o tọ