Nọmba 9:5 BM

5 Wọn sì ṣe é ní àṣáálẹ́ ọjọ́ kẹrinla oṣù kinni ní aṣálẹ̀ Sinai. Àwọn eniyan náà ṣe gẹ́gẹ́ bí OLUWA ti pa á láṣẹ fun wọn.

Ka pipe ipin Nọmba 9

Wo Nọmba 9:5 ni o tọ