Maku 11:32 BM

32 Àbí kí a wí pé, ‘Láti ọwọ́ eniyan ni?’ ” Wọ́n bẹ̀rù àwọn eniyan nítorí gbogbo eniyan ni ó gbà pé wolii tòótọ́ ni Johanu.

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:32 ni o tọ