Maku 11:33 BM

33 Wọ́n bá dá Jesu lóhùn pé, “Àwa kò mọ̀.”Nígbà náà ni Jesu sọ fún wọn pé, “Èmi náà kò ní sọ irú àṣẹ tí mo fi ń ṣe àwọn nǹkan wọnyi fun yín.”

Ka pipe ipin Maku 11

Wo Maku 11:33 ni o tọ