Maku 6:26 BM

26 Inú ọba bàjẹ́ pupọ, ṣugbọn nítorí ó ti ṣe ìlérí pẹlu ìbúra lójú àwọn tí ó wà níbi àsè, kò fẹ́ kọ̀ fún un.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:26 ni o tọ