Maku 6:27 BM

27 Lẹsẹkẹsẹ ọba rán ọmọ-ogun kan, ó pàṣẹ fún un kí ó gbé orí Johanu wá. Ó bá lọ, ó bẹ́ ẹ lórí ninu ilé ẹ̀wọ̀n.

Ka pipe ipin Maku 6

Wo Maku 6:27 ni o tọ