1. A. Ọba 10:29 YCE

29 Kẹkẹ́ kan ngoke o si njade lati Egipti wá fun ẹgbẹta ṣekeli fadakà, ati ẹṣin kan fun ãdọjọ: bẹ̃ni nwọn si nmu wá pẹlu nipa ọwọ wọn fun gbogbo awọn ọba awọn ọmọ Hiti ati fun awọn ọba Siria.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 10

Wo 1. A. Ọba 10:29 ni o tọ