1. A. Ọba 11:1 YCE

1 ṢUGBỌN Solomoni ọba fẹràn ọ̀pọ ajeji obinrin, pẹlu ọmọbinrin Farao, awọn obinrin ara Moabu, ti Ammoni, ti Edomu, ti Sidoni ati ti awọn ọmọ Hitti.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:1 ni o tọ