20 Arabinrin Tapenesi si bi Genubati ọmọ rẹ̀ fun u, Tapenesi si já a li ẹnu ọmu ni ile Farao: Genubati si wà ni ile Farao lãrin awọn ọmọ Farao,
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11
Wo 1. A. Ọba 11:20 ni o tọ