1. A. Ọba 11:21 YCE

21 Nigbati Hadadi si gbọ́ ni Egipti pe, Dafidi sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, ati pe Joabu olori-ogun si kú, Hadadi si wi fun Farao pe, rán mi lọ, ki emi ki o le lọ si ilu mi.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 11

Wo 1. A. Ọba 11:21 ni o tọ