1. A. Ọba 15:7 YCE

7 Njẹ iyokù iṣe Abijah ati gbogbo eyiti o ṣe, a kò ha kọ wọn sinu iwe ọ̀rọ ọjọ awọn ọba Juda? Ogun si wà lãrin Abijah ati Jeroboamu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 15

Wo 1. A. Ọba 15:7 ni o tọ