1. A. Ọba 20:29 YCE

29 Nwọn si dó, ekini tì ekeji ni ijọ meje. O si ṣe, li ọjọ keje, nwọn padegun, awọn ọmọ Israeli si pa ọkẹ marun ẹlẹsẹ̀ ninu awọn ara Siria li ọjọ kan.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:29 ni o tọ