1. A. Ọba 20:30 YCE

30 Sugbọn awọn iyokù salọ si Afeki, sinu ilu; odi si wolu ẹgbamẹtala-le-ẹgbẹrun ninu awọn enia ti o kù. Benhadadi si sa lọ, o si wá sinu ilu lati iyẹwu de iyẹwu.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 20

Wo 1. A. Ọba 20:30 ni o tọ