1. A. Ọba 21:15 YCE

15 O si ṣe, nigbati Jesebeli gbọ́ pe, a sọ Naboti li okuta, o si kú, Jesebeli sọ fun Ahabu pe, Dide! ki o si jogun ọgba-ajara Naboti, ara Jesreeli, ti o kọ̀ lati fi fun ọ fun owo; nitori Naboti kò si lãye ṣugbọn o kú.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 21

Wo 1. A. Ọba 21:15 ni o tọ