1. A. Ọba 21:16 YCE

16 O si ṣe, nigbati Ahabu gbọ́ pe, Naboti kú, ni Ahabu dide lati sọkalẹ lọ si ọgba-ajara Naboti, ara Jesreeli lati jogun rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 21

Wo 1. A. Ọba 21:16 ni o tọ