1. A. Ọba 22:22 YCE

22 Oluwa si wi fun u pe, Bawo? O si wipe, Emi o jade lọ, emi o si di ẹmi-eke li ẹnu gbogbo awọn woli rẹ̀. On si wipe, Iwọ o tàn a, iwọ o si bori pẹlu: jade lọ, ki o si ṣe bẹ̃.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:22 ni o tọ