1. A. Ọba 22:23 YCE

23 Njẹ nisisiyi, kiyesi i, Oluwa ti fi ẹmi-eke si ẹnu gbogbo awọn woli rẹ wọnyi, Oluwa si ti sọ ibi si ọ.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:23 ni o tọ