1. A. Ọba 22:49 YCE

49 Nigbana ni Ahasiah, ọmọ Ahabu, wi fun Jehoṣafati pe, Jẹ ki awọn iranṣẹ mi ba awọn iranṣẹ rẹ lọ ninu ọkọ̀. Ṣugbọn Jehoṣafati kọ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:49 ni o tọ