1. A. Ọba 22:50 YCE

50 Jehoṣafati si sùn pẹlu awọn baba rẹ̀, a si sin i pẹlu awọn baba rẹ̀ ni ilu Dafidi, baba rẹ̀: Jehoramu, ọmọ rẹ̀, si jọba ni ipò rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 22

Wo 1. A. Ọba 22:50 ni o tọ