45 Ati ikoko, ati ọkọ́, ati awo-koto; ati gbogbo ohun-elo wọnyi ti Hiramu ṣe fun ile Oluwa fun Solomoni ọba, jẹ ti idẹ didan.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 7
Wo 1. A. Ọba 7:45 ni o tọ