1. A. Ọba 8:65 YCE

65 Ati li àkoko na, Solomoni papejọ kan, ati gbogbo Israeli pẹlu rẹ̀, ajọ nla-nlã ni, lati iwọ Hamati titi de odò Egipti, niwaju Oluwa Ọlọrun wa, ijọ meje on ijọ meje, ani ijọ mẹrinla.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:65 ni o tọ