1. A. Ọba 8:66 YCE

66 Li ọjọ kẹjọ o rán awọn enia na lọ: nwọn si sure fun ọba, nwọn si lọ sinu agọ wọn pẹlu ayọ̀ ati inu-didun, nitori gbogbo ore ti Oluwa ti ṣe fun Dafidi, iranṣẹ rẹ̀, ati fun Israeli, enia rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. A. Ọba 8

Wo 1. A. Ọba 8:66 ni o tọ