15 Idi awọn asìnru ti Solomoni kojọ ni eyi; lati kọ́ ile Oluwa, ati ile on tikararẹ̀, ati Millo, ati odi Jerusalemu, ati Hasori ati Megiddo, ati Geseri.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9
Wo 1. A. Ọba 9:15 ni o tọ