16 Farao, ọba Egipti ti goke lọ, o si ti kó Geseri, o si ti fi iná sun u, o si ti pa awọn ara Kenaani ti ngbe ilu na, o si fi ta ọmọbinrin rẹ̀, aya Solomoni li ọrẹ.
Ka pipe ipin 1. A. Ọba 9
Wo 1. A. Ọba 9:16 ni o tọ