1. Sam 17:49 YCE

49 Dafidi si fi ọwọ́ rẹ̀ si inu apò, o si mu okuta kan lati ibẹ̀ wá, o si fì i, o si bà Filistini na niwaju, okuta na si wọ inu agbari rẹ̀ lọ, o si ṣubu dojubolẹ.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:49 ni o tọ