1. Sam 17:50 YCE

50 Bẹ̃ni Dafidi si fi kànakàna on okuta ṣẹgun Filistini na, o si bori Filistini na, o si pa a; ṣugbọn idà ko si lọwọ Dafidi.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:50 ni o tọ