1. Sam 17:57 YCE

57 Bi Dafidi si ti ti ibi ti o gbe pa Filistini na bọ̀, Abneri si mu u wá siwaju Saulu, ti on ti ori Filistini na lọwọ rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 17

Wo 1. Sam 17:57 ni o tọ