1 SAULU si sọ fun Jonatani ọmọ rẹ̀, ati fun gbogbo awọn iranṣẹ rẹ̀, pe, ki nwọn ki o pa Dafidi.
Ka pipe ipin 1. Sam 19
Wo 1. Sam 19:1 ni o tọ