1. Sam 18:30 YCE

30 Awọn ọmọ-alade Filistini si jade lọ: o si ṣe, lẹhin igbati nwọn lọ, Dafidi si huwa ọlọgbọ́n ju gbogbo awọn iranṣẹ Saulu lọ; orukọ rẹ̀ si ni iyìn jọjọ.

Ka pipe ipin 1. Sam 18

Wo 1. Sam 18:30 ni o tọ