1. Sam 19:8 YCE

8 Ogun si tun wà sibẹ, Dafidi si jade lọ, o si ba awọn Filistini jà, o si pa wọn pupọ; nwọn si sa niwaju rẹ̀.

Ka pipe ipin 1. Sam 19

Wo 1. Sam 19:8 ni o tọ