1. Sam 21:14 YCE

14 Nigbana ni Akiṣi wi fun awọn iranṣẹ rẹ̀ pe, Wõ, ẹnyin ri pe ọkunrin na nhuwà aṣiwere; njẹ nitori kini ẹnyin ṣe mu u tọ̀ mi wá?

Ka pipe ipin 1. Sam 21

Wo 1. Sam 21:14 ni o tọ