1. Sam 21:15 YCE

15 Mo ha ni aṣiwere fi ṣe? ti ẹnyin fi mu eyi tọ̀ mi wá lati hu iwa aṣiwere niwaju mi? eleyi yio ha wọ inu ile mi?

Ka pipe ipin 1. Sam 21

Wo 1. Sam 21:15 ni o tọ